Audio Music Download Nifemi David – Eyinju MP3 by Nifemi David
Get ready to be inspired! Download and Listen to this captivating new single, its inspiring lyrics, and the stunning official music video, titled Eyinju by a Renowned Gospel vocalist, spirit-led and soul-lifting Christian song minister Nifemi David Who is dedicated to using the gift of kingdom music to bring people closer to God, to inspire spiritual growth, healing, and restoration, and to foster a deeper sense of community, unity, and love among all who listen.
- Song Title: Mp3 Nifemi David Eyinju FREE DOWNLOAD Eyinju by Nifemi David
- Genre: Gospel
- Released: 2023
- Duration: 04:17
Download, Stream and Listen to this amazing single it’s absolutely free, and don’t forget to share with your friends and family for them to be a blessed through this powerful & melodius gospel music, and also don’t forget to drop your comment using the comment box below, we look forward to hearing from you. Thanks!! . #GospelJingle
Nifemi David Eyinju Lyrics
K’ato to d’omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d’omo loti mo’hun maa da o
Ogo fun eni to da mi
K’ato to d’omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d’omo loti mo’hun maa da o
Ogo fun eni to da mi
Ewe kan ko ni jabo
Koseyin Olodumare
Ohun ti mo maa da ti mo hun da lowo
Oti wa ninu eto babaa o
Eledaa to da mi
O mase ee oo
Ke’je to d’omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d’omo loti mo’hun maa da o
Ogo fun eni to da mi
Eto olorun nimi
Edaye ole Pemi lasise
Ninu eto olorun ni Mo wa
Eyi Lofi feto fun mi
Eto eyi logo
Tosemi yato
A o kan dami kan lasan
O laa dami ni iri ohun
And He took it personal
O pe mi ni ogo o
Ola ire
Ọrọ ibukun replete
Eyin sha leri ife oluwa simi iii pe
K’ato to d’omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d’omo loti mo’hun maa da o
Ogo fun eni to da mi
Kedaye masere ohun towa Leto
Mi o ni o duro sugbon makanju
Ma de sare asaju laye
Eleto ni’seda ko ni re o je
O waa ninu eto
Eto ate o lowo Boya o
Oti momi o
Kato dami sinu
Ki n to tinu jade
Loti somi di Mimo
Ayami Soto
Aye mi n bu ola fun ida ti o lasise e
Peki ni re se lodo emi
Eyinju baba
O n f’ogo fun hmmmm
(Aye emi naa to da)
O n f’ola fun
(O n fogo fun edara oto)
O n f’ogo fun hmmmm
(Ida to da mi Ola sise)
O n f’ola fun
(Modupe feleto to kami meto)
O n f’ogo fun hmmmm
(Ose e aye mi n fogo fun)
O n f’ola fun
K’eje to d’omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d’omo loti mo’hun maa da o
Ogo fun eni to da mi